Ékísódù 15:22 BMY

22 Nígbà náà ni Mósè ṣe amọ̀nà àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì jáde láti òkun pupa lọ sínú aṣálẹ̀ Ṣúrì. Wọ́n lọ ni ìrìn ọjọ́ mẹ́ta sínú ijù náà, wọn kò sì rí omi.

Ka pipe ipin Ékísódù 15

Wo Ékísódù 15:22 ni o tọ