Ékísódù 17:10 BMY

10 Jósúà se bí Mósè ti wí fún un, ó sì bá àwọn ará Ámélékì jagun; nígbà tí Mósè, Árónì àti Húrì lọ sí orí òkè náà.

Ka pipe ipin Ékísódù 17

Wo Ékísódù 17:10 ni o tọ