Ékísódù 17:2 BMY

2 Àwọn ènìyàn sì sọ̀ fún Mósè, wọ́n wí pé, “Fún wa ni omi mu.”Mósè dá wọn lóhùn wí pé, “Èéṣe ti ẹ̀yin fi ń bá mi jà? Èése ti ẹ̀yin fi ń dán Olúwa wò?”

Ka pipe ipin Ékísódù 17

Wo Ékísódù 17:2 ni o tọ