Ékísódù 17:7 BMY

7 Ó sì sọ orúkọ ibẹ̀ ni Másá (ìdánwò) àti Méríba (kíkùn) nítorí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀, wọ́n sì dán Olúwa wò, wọ́n wí pé, “Ǹjẹ́ Olúwa ń bẹ láàrin wa tàbí kò sí?”

Ka pipe ipin Ékísódù 17

Wo Ékísódù 17:7 ni o tọ