Ékísódù 18:3 BMY

3 Òun àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ méjèèjì. Orúkọ Àkọ́bí ń jẹ́ Gésómù (àjòjì); nítorí Mósè wí pé, “Èmi ń se àlejò ni ilẹ̀ àjòjì.”

Ka pipe ipin Ékísódù 18

Wo Ékísódù 18:3 ni o tọ