Ékísódù 20:4 BMY

4 “Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe ère fún ara rẹ ní àwòrán ohun kóhun tí ń bẹ ní òkè ọ̀run tàbí tí ń bẹ ní ayé, tàbí tí ń bẹ ní ìṣàlẹ̀ omi.

Ka pipe ipin Ékísódù 20

Wo Ékísódù 20:4 ni o tọ