Ékísódù 21:26 BMY

26 “Bí ọkùnrin kan bá lu ẹrúkùnrin tàbí ẹrúbìnrin rẹ̀ ní ojú, ti ojú náà sì fọ́, ó ni láti jẹ́ kí ẹrú náà lọ ní òmìnira fún ìtanràn ojú rẹ̀ ti ó fọ́.

Ka pipe ipin Ékísódù 21

Wo Ékísódù 21:26 ni o tọ