Ékísódù 21:6 BMY

6 Nígbà náà ni olówó rẹ̀ yóò mu wá sí iwájú ìdàjọ́. Òun yóò sì mú un lọ sí ẹnu ọ̀nà tàbí lọ sí ibi òpó, yóò sì fi ìlutí lu etí rẹ̀, òun yóò sì máa sin olówó rẹ̀ títí ayé.

Ka pipe ipin Ékísódù 21

Wo Ékísódù 21:6 ni o tọ