Ékísódù 22:15 BMY

15 Ṣùgbọ́n ti ó bá jẹ́ wí pé ó háyà ẹranko náà ni, kò ní láti san ẹ̀san padà, owó tí ó fi háyà ẹranko yìí ni yóò fi tan àdánù ẹranko tí ó kú.

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:15 ni o tọ