Ékísódù 22:24 BMY

24 Ìbínú mi yóò ru sókè. Èmi yóò sì fi idà pa ọ. Ìyàwó rẹ yóò di opó, àwọn ọmọ rẹ yóò sì di aláìní baba.

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:24 ni o tọ