Ékísódù 22:26 BMY

26 Bí ìwọ bá gba aṣọ aládùúgbò rẹ ni ẹ̀jẹ́, ìwọ gbọdọ̀ fún un padà kí òòrùn tó ó wọ̀,

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:26 ni o tọ