Ékísódù 23:29 BMY

29 Ṣùgbọ́n, èmi kò ni lé gbogbo wọn jáde ni ọdún kan soso, ki ilẹ̀ náà má ba à di ahoro, àwọn ẹranko búburú yóò sì ti pọ̀ jù fún ọ.

Ka pipe ipin Ékísódù 23

Wo Ékísódù 23:29 ni o tọ