Ékísódù 23:7 BMY

7 Má ṣe lọ́wọ́ nínú ẹ̀sùn èké, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò gbọdọ̀ pa aláìṣẹ̀ tàbi olódodo ènìyàn, nítorí èmi kò ní dá ẹlẹ́bí láre.

Ka pipe ipin Ékísódù 23

Wo Ékísódù 23:7 ni o tọ