Ékísódù 24:7 BMY

7 Nígbà náà ni ó sì mú ìwé májẹ̀mú, ó sì kà á sí àwọn ènìyàn. Wọ́n dáhùn pé, “Àwa yóò ṣe gbogbo ohun tí Olúwa wí: Àwa yóò sì gbọ́ràn.”

Ka pipe ipin Ékísódù 24

Wo Ékísódù 24:7 ni o tọ