Ékísódù 25:19 BMY

19 Ṣe kérúbù kan sí igun kìn-ín-ní àti kérúbù kejì sí igun kejì kí kérúbù náà jẹ́ irú kan náà ní igun méjèèjì.

Ka pipe ipin Ékísódù 25

Wo Ékísódù 25:19 ni o tọ