Ékísódù 25:22 BMY

22 Níbẹ̀, ni òkè ìtẹ́, ní àárin kérúbù méjèèjì ti ó wà ni orí àpótí ẹ̀rí ni èmi yóò ti pàdé rẹ, ti èmi yóò sì fún ọ ní àwọn òfin mi fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ékísódù 25

Wo Ékísódù 25:22 ni o tọ