Ékísódù 25:9 BMY

9 Gẹ́gẹ́ bí gbogbo èyí ti mo fi hàn ọ́, nípa àpẹẹrẹ àgọ́, àti àpẹẹrẹ gbogbo ohun èlò inú rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin kí ó sì ṣe é.

Ka pipe ipin Ékísódù 25

Wo Ékísódù 25:9 ni o tọ