Ékísódù 26:6 BMY

6 Nígbà náà ṣe àádọ́ta (50) ìkọ́ yóòkù kí o sì lò wọ́n láti fi fa àwọn aṣọ títa náà papọ̀, nítorí náà àgọ́ náà yóò jẹ́ ọ̀kan.

Ka pipe ipin Ékísódù 26

Wo Ékísódù 26:6 ni o tọ