Ékísódù 28:11 BMY

11 Iṣẹ́ ọnà òkúta fínfín, bí ìfín èdìdì àmì, ni ìwọ yóò fún òkúta méjèèjì gẹ́gẹ́ bí orúkọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì: ìwọ yóò sì dè wọ́n sí ojú ìdè wúrà.

Ka pipe ipin Ékísódù 28

Wo Ékísódù 28:11 ni o tọ