Ékísódù 29:35 BMY

35 “Bàyìí ni ìwọ yóò sìṣe fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ bí ohun gbogbo ti mo paláṣẹ fún ọ, ọjọ́ méje ni ìwọ yóò fi yà wọ́n sí mímọ́.

Ka pipe ipin Ékísódù 29

Wo Ékísódù 29:35 ni o tọ