Ékísódù 30:33 BMY

33 Ẹnikẹ́ni tí ó bá po irú rẹ̀, tàbí ẹnikẹ́ni tí ó bá fi sára ẹnìkankan yàtọ̀ sí àlùfáà, a ó gé e kúrò nínú àwọn ènìyàn rẹ̀.’ ”

Ka pipe ipin Ékísódù 30

Wo Ékísódù 30:33 ni o tọ