Ékísódù 31:16 BMY

16 Nítorí náà ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò se máa pa ọjọ ìsinmi mọ́, ẹ máa ṣe àkíyèsí rẹ̀ dé ìrandíràn tó ń bọ̀ bí i májẹ̀mu títí láé.

Ka pipe ipin Ékísódù 31

Wo Ékísódù 31:16 ni o tọ