Ékísódù 33:9 BMY

9 Bí Mósè ṣe wọ inú àgọ́ náà, ọ̀wọ̀n àwọ̀ọsánmọ̀ yóò sọ̀kalẹ̀, yóò sì dúró sí ẹnu ọnà, nígbà tí Olúwa ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú Mósè.

Ka pipe ipin Ékísódù 33

Wo Ékísódù 33:9 ni o tọ