Ékísódù 34:27 BMY

27 Olúwa sì wí fún Mósè pé, “Kọ àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí sílẹ̀, nítorí nípa àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ni èmi bá ìwọ àti Ísírẹ́lì dá májẹ̀mú.”

Ka pipe ipin Ékísódù 34

Wo Ékísódù 34:27 ni o tọ