Ékísódù 38:2 BMY

2 Ó ṣe ìwo sí igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, nítorí kí ìwo àti pẹpẹ náà lè jẹ́ ọ̀kan, ó sì bo pẹpẹ náà pẹ̀lú idẹ.

Ka pipe ipin Ékísódù 38

Wo Ékísódù 38:2 ni o tọ