Ékísódù 38:28 BMY

28 Ó lo òjìdínlẹ́gbẹ̀san ó lé mẹ́ẹ̀dogun sékélì (1,775 shekels) ìwọ̀n ogún gíráàmù ni ó fi ṣe ìkọ́ fún òpó náà, láti fi bo orí òpó náà àti láti fi ṣe ìgbànú wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 38

Wo Ékísódù 38:28 ni o tọ