Ékísódù 38:7 BMY

7 Ó sì fi òpó náà bọ inú òrùka, nítorí kí ó lè wà ní ìhà pẹpẹ náà láti máa fi gbé e. Ó sì sé e ní oníhò nínú.

Ka pipe ipin Ékísódù 38

Wo Ékísódù 38:7 ni o tọ