43 Mósè bẹ iṣẹ́ náà wò, ó sì rí i wí pé wọ́n ti ṣe é gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pà ṣẹ. Nítorí náà Mósè sì bùkún fún wọn.
Ka pipe ipin Ékísódù 39
Wo Ékísódù 39:43 ni o tọ