Ékísódù 40:21 BMY

21 Ó sì gbé àpótí náà wá sínú àgọ́; ó sì sọ aṣọ títa, ó sì ta á bo àpótí ẹ̀rí, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún-un.

Ka pipe ipin Ékísódù 40

Wo Ékísódù 40:21 ni o tọ