Ékísódù 40:33 BMY

33 Mósè sì gbé àgbàlá tí ó yí Àgọ́ náà kà ró àti pẹpẹ, ó sì ta aṣọ títa ti ẹnu ọ̀nà sí àgbàlá náà. Bẹ́ẹ̀ Mósè ṣe parí iṣẹ náà

Ka pipe ipin Ékísódù 40

Wo Ékísódù 40:33 ni o tọ