Ékísódù 40:35 BMY

35 Mósè kò sì lè wọ inú Àgọ́ àjọ, nítorí àwọ́ọ́sánmọ̀ wà lórí rẹ, ògo Olúwa sì ti kún inú Àgọ́ náà.

Ka pipe ipin Ékísódù 40

Wo Ékísódù 40:35 ni o tọ