Ékísódù 40:4 BMY

4 Gbé tábìlì náà wọ ilé, kí o sì tò àwọn ohun tí ó jẹ́ tirẹ̀ lé e lórí. Nígbà náà gbé ọ̀pá fìtílà wọlé, kí o sì to àwọn fìtílà rẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 40

Wo Ékísódù 40:4 ni o tọ