Ékísódù 40:9 BMY

9 “Mú òróró ìtasórí, kí ó sì ta á sára Àgọ́ náà àti ohun gbogbo tí ó wà nínú rẹ̀: yà pẹpẹ sí mímọ́ àti gbogbo ọ̀sọ́ rẹ̀, yóò sì jẹ́ mímọ́.

Ka pipe ipin Ékísódù 40

Wo Ékísódù 40:9 ni o tọ