Ékísódù 5:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n ọba Éjíbítì sọ wí pé, “Mósè àti Árónì, èése ti ẹ̀yin fi mú àwọn ènìyàn kúrò lẹ́nu iṣẹ́ wọn? Ẹ padà sẹ́nu iṣẹ́ yín.”

Ka pipe ipin Ékísódù 5

Wo Ékísódù 5:4 ni o tọ