Ékísódù 7:11 BMY

11 Fáráò sì pe àwọn amòye, àwọn osó àti àwọn onídán ilẹ̀ Éjíbítì jọ, wọ́n sì fi idán wọn ṣe ohun tí Mósè àti Árónì ṣe.

Ka pipe ipin Ékísódù 7

Wo Ékísódù 7:11 ni o tọ