Ékísódù 8:7 BMY

7 Ṣùgbọ́n àwọn onídan ilẹ̀ Éjíbítì ṣe bákan náà pẹ̀lú agbára òkùnkùn wọn. Àwọn náà mú kí ọ̀pọ̀lọ́ gun wá sí orí ilẹ̀ Éjíbítì.

Ka pipe ipin Ékísódù 8

Wo Ékísódù 8:7 ni o tọ