Ékísódù 9:3 BMY

3 Ọwọ́ Olúwa yóò mú àrùn búburú wá sí ara ẹran ọ̀sìn nínú oko, sí ara ẹsin, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, rànkunmí, màlúù, àgùntàn àti ewúrẹ́ yín.

Ka pipe ipin Ékísódù 9

Wo Ékísódù 9:3 ni o tọ