Ẹ́sírà 3:11 BMY

11 Pẹ̀lú ìyìn àti ọpẹ́ ni wọ́n kọrin sí Olúwa:“Ó dára;ìfẹ́ rẹ̀ sí Ísírẹ́lì dúró títí láé.”Gbogbo àwọn ènìyàn sì fi ohùn ariwo ńlá yin Olúwa, nítorí tí a ti fi ìpìlẹ̀ ilé Olúwa lélẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 3

Wo Ẹ́sírà 3:11 ni o tọ