Ẹ́sírà 3:10 BMY

10 Nígbà tí àwọn ọ̀mọ̀lé gbé ìpìlẹ̀ ilé Olúwa kalẹ̀, àwọn àlùfáà nínú aṣọ iṣẹ́ àlùfáà wọn pẹ̀lú fèrè, àti àwọn ará Léfì (Àwọn ọmọ Ásáfù) pẹ̀lú Kíńbálì, dúró ní ipò wọn láti yin Olúwa, bí Dáfídì ọba Ísírẹ́lì ti fi lélẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 3

Wo Ẹ́sírà 3:10 ni o tọ