9 Jéṣúà àti àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ àti Kádímíélì àti àwọn ọmọ rẹ̀ (àwọn ìránṣẹ́ Hódáfíà) àti àwọn ọmọ Hénádádì àti àwọn ọmọ wọn àti àwọn arákùnrin wọn—gbogbo ará Léfì—parapọ̀ láti bojútó àwọn òṣìṣẹ́ náà tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ lórí í kíkọ́ ilé Ọlọ́run.