Ẹ́sírà 6:13 BMY

13 Nígbà náà, nítorí àṣẹ tí ọba Dáríúsì pa, Táténáì, Baálẹ̀ ti agbégbé Yúfúrátè, àti Ṣétarì-Bóṣénáì pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́gbẹ́ wọn pa á mọ́ láì yí ọ̀kan padà.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 6

Wo Ẹ́sírà 6:13 ni o tọ