Ẹ́sírà 7:20 BMY

20 Ohunkóhun mìíràn tí o bá nílò fún tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run rẹ tí ó sì ní láti pèsè, o lè mú u láti inú ìṣúra ọba.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 7

Wo Ẹ́sírà 7:20 ni o tọ