Ẹ́sírà 7:6 BMY

6 Ẹ́sírà yìí gòkè wá láti Bábílónì. Olùkọ́ tí ó ní ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa òfìn Mósè, èyí tí Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ti fi fún wọn. Ọba sì fi gbogbo ohun tí ó béèrè fún un, nítorí ọwọ́ Olúwa Ọlọ́run wà lára rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 7

Wo Ẹ́sírà 7:6 ni o tọ