Ẹ́sírà 7:7 BMY

7 Ní ọdún keje ọba Aritaṣéṣéṣì díẹ̀ lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, àwọn akọrin, àwọn aṣọ́nà àti àwọn tí ń ṣiṣẹ́ nínú tẹ́ḿpìlì náà gòkè wá sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 7

Wo Ẹ́sírà 7:7 ni o tọ