Ẹ́sítà 1:1 BMY

1 Èyí ni ohun tó ṣẹlẹ̀ ní ìgbà Sérísésì, tí ó jọba lórí ẹ̀tàdínláàdóje ìletò bẹ̀rẹ̀ láti Índíà títí ó fi dé Etiópíà. (Kúsì)

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 1

Wo Ẹ́sítà 1:1 ni o tọ