Ẹ́sítà 1:7 BMY

7 Kọ́ọ̀bù wúrà onídìí-odó ni a fi ń bu wáìnì fún wọn mu, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì yàtọ̀ sí èkejì, wáìnì ọba pọ̀ púpọ̀, gẹ́gẹ́ bí ọba ṣe lawọ́ sí.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 1

Wo Ẹ́sítà 1:7 ni o tọ