Ẹ́sítà 2:11 BMY

11 Ní ojoojúmọ́ ni Módékáì máa ń rìn ní iwájú ilé àwọn obìnrin láti wo bí Ẹ́sítà ṣe wà àti ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí i.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:11 ni o tọ