Ẹ́sítà 2:6 BMY

6 Ẹni tí Nebukadinésárì ọba Bábílónì ti gbé lọ sí ìgbèkùn láti Jérúsálẹ́mù, lára àwọn tí wọ́n kó ní ìgbèkùn pẹ̀lú ọba Jéóhákímù ọba Júdà.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:6 ni o tọ