Ẹ́sítà 3:15 BMY

15 Àwọn ìránṣẹ́ náà sì jáde, wọ́n tẹ̀síwájú nípa àṣẹ ọba, ìkéde náà sì jáde ní ìlé ìsọ́ ti Ṣúsà. Ọba àti Hámánì jókòó wọ́n ń mu, ṣùgbọ́n ìlú Ṣúsà wà nínú ìdààmú.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 3

Wo Ẹ́sítà 3:15 ni o tọ