Ẹ́sítà 3:7 BMY

7 Ní ọdún kejìlá ọba Ṣérísésì, ní oṣù kìn-ín-ní, èyí ni oṣù nísánì, wọ́n da Púrì (èyí tí í ṣe, ìbò) ní iwájú Hámánì láti yan ọjọ́ kan àti oṣù, ìbò náà sì wáyé ní oṣù kejìlá, oṣù Ádárì.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 3

Wo Ẹ́sítà 3:7 ni o tọ